Jẹnẹsisi 25:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Iye ọdún tí Iṣimaeli gbé láyé jẹ́ ọdún mẹtadinlogoje (137). Nígbà tí ó kú a sin ín pẹlu àwọn eniyan rẹ̀.

Jẹnẹsisi 25

Jẹnẹsisi 25:16-19