Jẹnẹsisi 25:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) Abrahamu fẹ́ aya mìíràn, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ketura. Ketura bí Simirani, Jokiṣani, Medani, Midiani