Jẹnẹsisi 24:67 BIBELI MIMỌ (BM)

Isaaki bá mú Rebeka wọ inú àgọ́ Sara ìyá rẹ̀, Rebeka sì di aya rẹ̀, Isaaki sì fẹ́ràn rẹ̀. Nígbà yìí ni Isaaki kò tó ṣọ̀fọ̀ ìyá rẹ̀ mọ́.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:60-67