Jẹnẹsisi 24:66 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n pàdé Isaaki, iranṣẹ náà ròyìn gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún un.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:64-67