Jẹnẹsisi 24:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Iranṣẹ náà bá ti ọwọ́ rẹ̀ bọ abẹ́ itan Abrahamu oluwa rẹ̀, ó sì búra láti ṣe ohun tí Abrahamu pa láṣẹ fún un.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:7-18