Jẹnẹsisi 24:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Iranṣẹ náà mú mẹ́wàá ninu àwọn ràkúnmí oluwa rẹ̀, ó gba oríṣìíríṣìí ẹ̀bùn àtàtà lọ́wọ́ oluwa rẹ̀, ó jáde lọ sí ilẹ̀ Mesopotamia, sí ìlú Nahori.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:3-13