Jẹnẹsisi 24:44 BIBELI MIMỌ (BM)

tí ó bá wí fún mi pé, “Omi nìyí, mu, n óo sì pọn fún àwọn ràkúnmí rẹ pẹlu”, nígbà náà ni n óo mọ̀ pé òun ni obinrin náà tí ìwọ OLUWA ti yàn láti jẹ́ aya ọmọ oluwa mi.’

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:40-50