Jẹnẹsisi 24:43 BIBELI MIMỌ (BM)

bí mo ti dúró nídìí kànga yìí, ọmọbinrin tí ó bá wá pọnmi, tí mo bá sì sọ fún pé, jọ̀wọ́, fún mi lómi mu ninu ìkòkò omi rẹ,

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:40-46