Jẹnẹsisi 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun ní, “Mú Isaaki ọmọ rẹ kan ṣoṣo tí o fẹ́ràn, kí o lọ sí ilẹ̀ Moraya, kí o sì fi ọmọ náà rú ẹbọ sísun lórí ọ̀kan ninu àwọn òkè tí n óo júwe fún ọ.”

Jẹnẹsisi 22

Jẹnẹsisi 22:1-11