Jẹnẹsisi 22:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn nǹkan wọnyi, Ọlọrun dán Abrahamu wò, ó ní, “Abrahamu!” Abrahamu dáhùn pé, “Èmi nìyí.”

Jẹnẹsisi 22

Jẹnẹsisi 22:1-2