Jẹnẹsisi 21:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, Sara rí ọmọ tí Hagari, ará Ijipti bí fún Abrahamu, níbi tí ó ti ń bá Isaaki, ọmọ rẹ̀, ṣeré.

Jẹnẹsisi 21

Jẹnẹsisi 21:7-11