Jẹnẹsisi 21:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Sara bá pe Abrahamu, ó sọ fún un pé, “Lé ẹrubinrin yìí jáde pẹlu ọmọ rẹ̀, nítorí pé ọmọ ẹrubinrin yìí kò ní jẹ́ àrólé pẹlu Isaaki ọmọ mi.”

Jẹnẹsisi 21

Jẹnẹsisi 21:5-11