Jẹnẹsisi 20:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wí fún Sara náà pé, “Mo ti kó ẹgbẹrun (1,000) owó fadaka fún arakunrin rẹ, èyí ni láti wẹ̀ ọ́ mọ́ lójú gbogbo àwọn tí wọ́n wà pẹlu rẹ, nisinsinyii, o ti gba ìdáláre lójú gbogbo eniyan.”

Jẹnẹsisi 20

Jẹnẹsisi 20:7-17