Jẹnẹsisi 20:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Abimeleki tún wí fún un pé, “Wo gbogbo ilẹ̀ yìí, èmi ni mo ni ín, yan ibi tí ó bá wù ọ́ láti gbé.”

Jẹnẹsisi 20

Jẹnẹsisi 20:5-18