Jẹnẹsisi 18:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jẹ́ kí wọ́n bu omi wá kí ẹ fi ṣan ẹsẹ̀, kí ẹ sì sinmi díẹ̀ lábẹ́ igi níhìn-ín.

Jẹnẹsisi 18

Jẹnẹsisi 18:1-10