Jẹnẹsisi 18:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wí pé, “Ẹ̀yin oluwa mi, bí inú yín bá dùn sí mi, ẹ jọ̀wọ́, ẹ má kọjá lọ bẹ́ẹ̀ láìdúró díẹ̀ lọ́dọ̀ èmi iranṣẹ yín!

Jẹnẹsisi 18

Jẹnẹsisi 18:1-9