Jẹnẹsisi 18:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Abrahamu bá súnmọ́ OLUWA, ó wí pé, “O ha gbọdọ̀ pa àwọn olódodo run pẹlu àwọn eniyan burúkú bí?

Jẹnẹsisi 18

Jẹnẹsisi 18:17-30