Jẹnẹsisi 18:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin náà bá kúrò níbẹ̀, wọ́n gba ọ̀nà Sodomu lọ, ṣugbọn Abrahamu tún dúró níwájú OLUWA níbẹ̀.

Jẹnẹsisi 18

Jẹnẹsisi 18:15-30