Jẹnẹsisi 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọ̀sán gangan ọjọ́ kan, OLUWA fara han Abrahamu bí ó ti jókòó ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ rẹ̀, lẹ́bàá igi Oaku ti Mamure.

Jẹnẹsisi 18

Jẹnẹsisi 18:1-10