Jẹnẹsisi 17:27 BIBELI MIMỌ (BM)

ati gbogbo àwọn ọkunrin tí wọ́n wà ninu ilé rẹ̀, ati àwọn tí wọ́n bí sinu ilé rẹ̀, ati àwọn tí wọ́n fi owó rà, gbogbo wọn ni wọ́n kọ nílà abẹ́ pẹlu rẹ̀.

Jẹnẹsisi 17

Jẹnẹsisi 17:17-27