Jẹnẹsisi 16:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Abramu bá Hagari lòpọ̀, Hagari sì lóyún. Nígbà tí ó rí i pé òun lóyún, ó bẹ̀rẹ̀ sí fi ojú tẹmbẹlu Sarai, oluwa rẹ̀.

Jẹnẹsisi 16

Jẹnẹsisi 16:1-8