Jẹnẹsisi 16:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ọdún mẹ́wàá tí Abramu ti dé ilẹ̀ Kenaani ni Sarai, aya rẹ̀ fa Hagari, ará Ijipti, ẹrubinrin rẹ̀ fún un, láti fi ṣe aya.

Jẹnẹsisi 16

Jẹnẹsisi 16:1-4