Jẹnẹsisi 15:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Abramu dáhùn pé, “OLUWA Ọlọrun, kí ni o óo fún mi, n kò tíì bímọ títí di ìsinsìnyìí! Ṣé Elieseri ará Damasku yìí ni yóo jẹ́ àrólé mi ni?

Jẹnẹsisi 15

Jẹnẹsisi 15:1-12