Jẹnẹsisi 15:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn nǹkan wọnyi, OLUWA bá Abramu sọ̀rọ̀ lójú ìran, ó ní, “Má bẹ̀rù Abramu, n óo dáàbò bò ọ́, èrè rẹ yóo sì pọ̀ pupọ.”

Jẹnẹsisi 15

Jẹnẹsisi 15:1-4