Jẹnẹsisi 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbógun ti Kedorilaomeri, ọba Elamu, Tidali, ọba Goiimu, Amrafeli, ọba Babiloni ati Arioku, ọba Elasari. Ọba mẹrin dojú kọ ọba marun-un.

Jẹnẹsisi 14

Jẹnẹsisi 14:1-17