Jẹnẹsisi 14:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni wọ́n tó yipada tí wọ́n sì wá sí Enmiṣipati (tí ó tún ń jẹ́ Kadeṣi), wọ́n sì ṣẹgun gbogbo ilẹ̀ àwọn ará Amaleki ati ti àwọn ará Amori tí ń gbé Hasasoni Tamari.

Jẹnẹsisi 14

Jẹnẹsisi 14:1-8