Jẹnẹsisi 13:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Abramu ń gbé ilẹ̀ Kenaani, Lọti sì ń gbé ààrin àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè odò Jọdani, ó pàgọ́ rẹ̀ títí dé Sodomu.

Jẹnẹsisi 13

Jẹnẹsisi 13:6-17