Jẹnẹsisi 13:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Lọti bá yan gbogbo agbègbè odò Jọdani fún ara rẹ̀, ó sì lọ sí ìhà ìlà oòrùn. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe takété sí ara wọn.

Jẹnẹsisi 13

Jẹnẹsisi 13:8-18