Jẹnẹsisi 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Abramu mú Sarai iyawo rẹ̀, ati Lọti, ọmọ arakunrin rẹ̀ lọ́wọ́ lọ, ati gbogbo ohun ìní wọn ati gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n jẹ́ tiwọn ní Harani. Wọ́n jáde, wọ́n gbọ̀nà ilẹ̀ Kenaani.Nígbà tí wọ́n dé ilẹ̀ Kenaani,

Jẹnẹsisi 12

Jẹnẹsisi 12:1-14