Jẹnẹsisi 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Abramu ṣe jáde lọ, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti sọ fún un, Lọti sì bá a lọ. Abramu jẹ́ ẹni ọdún marundinlọgọrin nígbà tí ó jáde kúrò ní Harani.

Jẹnẹsisi 12

Jẹnẹsisi 12:1-14