Jẹnẹsisi 12:2 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo sọ ọ́ di orílẹ̀-èdè ńlá, n óo bukun ọ, n óo sì sọ orúkọ rẹ di ńlá, tóbẹ́ẹ̀ tí o óo jẹ́ ibukun fún àwọn eniyan.

Jẹnẹsisi 12

Jẹnẹsisi 12:1-10