Jẹnẹsisi 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, Ọlọrun sọ fún Abramu pé, “Jáde kúrò ní ilẹ̀ rẹ, láàrin àwọn ìbátan rẹ, ati kúrò ní ilé baba rẹ lọ sí ilẹ̀ kan tí n óo fi hàn ọ́.

Jẹnẹsisi 12

Jẹnẹsisi 12:1-7