Jẹnẹsisi 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ fún ara wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí á ṣe bíríkì, kí á sì sun wọ́n jiná dáradára.” Bíríkì ni wọ́n lò dípò òkúta, wọ́n sì lo ọ̀dà ilẹ̀ dípò ọ̀rọ̀.

Jẹnẹsisi 11

Jẹnẹsisi 11:1-11