Jẹnẹsisi 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àwọn eniyan ṣe ń ṣí káàkiri ní ìhà ìlà oòrùn, wọ́n rí ilẹ̀ tí ó tẹ́jú ní agbègbè Babiloni, wọ́n sì tẹ̀dó sibẹ.

Jẹnẹsisi 11

Jẹnẹsisi 11:1-12