Jẹnẹsisi 10:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdílé àwọn ọmọ Noa ni wọ́n jẹ́, gẹ́gẹ́ bí ìran wọn ní orílẹ̀-èdè wọn. Lára wọn ni àwọn orílẹ̀-èdè ti tàn ká gbogbo ayé lẹ́yìn ìkún omi.

Jẹnẹsisi 10

Jẹnẹsisi 10:24-32