Jẹnẹsisi 10:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ni ọmọ Ṣemu, ní ìdílé ìdílé wọn, olukuluku ní agbègbè tirẹ̀. Oríṣìíríṣìí orílẹ̀-èdè ni wọ́n, wọ́n sì ń sọ oríṣìíríṣìí èdè.

Jẹnẹsisi 10

Jẹnẹsisi 10:28-32