Jẹnẹsisi 10:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣemu, ẹ̀gbọ́n Jafẹti, náà bí àwọn ọmọ tirẹ̀, òun ni baba ńlá gbogbo àwọn ọmọ Eberi.

Jẹnẹsisi 10

Jẹnẹsisi 10:15-28