Jẹnẹsisi 10:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Hamu nìwọ̀nyí ní ìdílé ìdílé wọn, olukuluku ní agbègbè tirẹ̀, oríṣìíríṣìí orílẹ̀-èdè ni wọ́n, wọ́n sì ń sọ oríṣìíríṣìí èdè.

Jẹnẹsisi 10

Jẹnẹsisi 10:10-23