Jẹnẹsisi 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun dá ìmọ́lẹ̀ ńlá meji: ó dá oòrùn láti máa jọba ọ̀sán, ati òṣùpá láti máa jọba òru, ó sì dá àwọn ìràwọ̀ pẹlu.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:8-25