Jẹnẹsisi 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

kí wọ́n sì jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ní ojú ọ̀run láti máa tàn sórí ilẹ̀ ayé, ó sì rí bẹ́ẹ̀.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:9-25