Ìwé Òwe 28:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọ́gbọ́n ọmọ ni ọmọ tí ó pa òfin mọ́,ṣugbọn ẹni tí ń bá àwọn wọ̀bìà rìn, ń dójúti baba rẹ̀.

Ìwé Òwe 28

Ìwé Òwe 28:1-15