Ìwé Òwe 13:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọlọ́gbọ́n ọmọ a máa gba ẹ̀kọ́ baba rẹ̀,ṣugbọn ẹlẹ́yà kì í gbọ́ ìbáwí.

2. Eniyan rere a máa rí ire nítorí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀,ṣugbọn ohun tí àwọn ẹlẹ́tàn ń fẹ́ ni ìwà jàgídíjàgan.

Ìwé Òwe 13