Eniyan rere a máa rí ire nítorí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀,ṣugbọn ohun tí àwọn ẹlẹ́tàn ń fẹ́ ni ìwà jàgídíjàgan.