Ìwé Òwe 11:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan burúkú bá kú,ìrètí wọn yóo di asán,bẹ́ẹ̀ ni ìrètí àwọn tí kò mọ Ọlọrun yóo di òfo.

Ìwé Òwe 11

Ìwé Òwe 11:1-13