Ìwé Òwe 11:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwà òdodo àwọn olóòótọ́ yóo gbà wọ́n,ṣugbọn ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ àwọn ọ̀dàlẹ̀ yóo dè wọ́n nígbèkùn.

Ìwé Òwe 11

Ìwé Òwe 11:5-12