Isikiẹli 9:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá gbọ́ tí ọkunrin tí ó wọ aṣọ funfun, tí ó sì ní àpótí ìkọ̀wé lẹ́gbẹ̀ẹ́, ń jábọ̀ pé, “Mo ti ṣe bí o ti pàṣẹ fún mi.”

Isikiẹli 9

Isikiẹli 9:7-11