Isikiẹli 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, mo wo orí àwọn Kerubu, mo rí kinní kan róbótó róbótó, wọ́n dàbí òkúta safire, ìrísí wọn dàbí ìtẹ́.

Isikiẹli 10

Isikiẹli 10:1-2