Isikiẹli 7:22 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo mójú kúrò lọ́dọ̀ wọn, kí wọ́n lè sọ ibi dídára mi di eléèérí. Àwọn ọlọ́ṣà yóo wọnú rẹ̀, wọn yóo sì sọ ọ́ di eléèérí.

Isikiẹli 7

Isikiẹli 7:18-27