Isikiẹli 7:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “N óo sọ wọ́n di ìjẹ fún àwọn àjèjì, n óo sì fi wọ́n ṣe ìkógun fún àwọn eniyan burúkú ilé ayé. Wọn óo sọ wọ́n di ohun eléèérí.

Isikiẹli 7

Isikiẹli 7:14-24