Isikiẹli 5:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Mú díẹ̀ ninu èyí tí o dì sí etí ẹ̀wù, jù ú sinu iná kí ó jóná; iná yóo sì ti ibẹ̀ ṣẹ́ sí gbogbo ilé Israẹli.”

Isikiẹli 5

Isikiẹli 5:1-7